FIRST TERM EXAMINATION NAME : _______________________________________

CLASS : PRIMARY FOUR

SUBJECT : YORUBA STUDIES

DURATION: 1HOUR.

INSTRUCTION : ANSWER ALL QUESTIONS.

Ka aroko yii ki osi dahun ibeere ti o telee

Ohun ti aba je sikun ni I so emir oOhun ti a ba fi ko omo eni ni dogun fun unEda to fomo sile lai ko logbon,Ton ko ilen to si n ko aase joKo ranti pe ile yoo di ile eni eleniAase yoo di ase omo elomiranOgun yoo di ogun elebi gbogboTabi ta ni ko modaju wipeOmo ti ako ko ni yoo gbe ile ti ako ta?Tabi igba ti omo ya ode eniyanTi ko ja fafa laye nko,ki ni ko tun da leyin aginrinje-Omo ti n rungun omo pala- nta omoOmo apa ti ko tile taOmo ti ta gbogbo ohun ti baba ni tan jeun?Eje ka ronu wo fun igbeyin omo eniKa roju ko won logbon yanju korokoro

Dahun awon ibere wonyi

kini ohun so emi roo …………………………………………………………………………… ni n di ogun fún

.eda ti ko ba ko omo re ni ile re yoo di ti …….……………….

ni yoo gbe ile ti a ba ko ta.

omo ……. ni ko tile ta

Ko awon figo yii ni onka Yoruba

100 ………………………………

115 …………………………………

Ko onka Yoruba yii ni figo Aadofa ………………………………………

mokanlelogorun-un ………………………

Pin awon oro wonyi ni isori ki o si ko oye igba ti a pin awon oro onisileebu naa sii.

ALARINKIRIEFUFULELEEFUNSETANALAGBADAINA

———– ni o le wure fun eniyan. (a) oga b) omode d) koosi

————– ni apa to se julo ninu ihun silebu kookan (a) ori odo silebu b)odo silebu d) ihun silebu

————- je ona ti an lo lati fi ko awon omode ni iwa omoluabi yala ni ita tabi lawujo. (a) ise ile b) eko ile d) sileebu

————- ni ona ti a nlo lati fi ko awon omode ni eko adayeba.(a) eko ile b) iwa omoluabi d) iwa odaran

—————- ati —————– wa lara eko ile.(a) ibuni ati ija b) ise si ofin d) ikinni ati siso otito

————– ni iwulo ise ile lawujo. (a) isokan idile b) ibaje omode d) ejo wewe

.————— je asopo okunrin ati obirin ni ona olorun,ona ibile ati ona ofin (a) ise ile b) igbeyawo d) iwa omoluabi

———— ati ————- ni orisirisi eto igbeyawo to w ani ile Yoruba (a) igbeyawo abinibi ati igbeyawo ode oni b) igbeyawo atijo ati igbeyawo ojo iwaju d) igbeyawo isonu ati igbeyawo igboyun

Ede Yoruba maa n muni te lawujo. beeni abi beeko

A le fi ede Yoruba ki eniyan. Beeni abi beeko

A le lo ede Yoruba lati fi pon eniyan le beeni abi beeko

A le lo ede Yoruba lati fi kewi beeni abi beeko

APA KEJI

Kini ise ile?

Ko ise ile marun ni lawujo.

Kini igbeyawo

b ko asa meta ninu igbese igbeyawo.

Ko awon idana meji ti o wa

b ko meta ninu awon ohun idana ojo igbeyawo.


Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *