First Term Lesson Note for Week Four
Class : Nursery One
Age : 4 years
Subject : Yoruba Language
Topic: Ásà Orúkọ jíjẹ ní ilé Yorùbá
Duration: 80 minutes
Period : Double Periods
Reference Book : Eko Èdè Yorùbá Ìwé kika fún àwọn ọmọ
Online Resources
Lagos State Unified Schemes of Work for Early childhood
Instructional Material : Charts on Yorùbá names and meaning
Behavioural Objectives : By the end of the lesson, learners will be able to :
i. Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yóò lè dárúkọ amutorun wa
ii. Dídá Orúkọ abiso mọ
Content:
Orúkọ sì sọ ní ilé Yorùbá pín sí ona mẹta :
A.) Orúkọ amutorunwa
B.) Orúkọ Abiso àti
D.) Orúkọ Oríkì
Orúkọ amutorunwa je orúkọ tí ọmọ tí a bí mú wá sí ilé ayé. I pàṣẹ bí wọ́n ṣe bí ọmọ ni a a ń wo kí ató sọmọ lórúkọ.
Fún àpẹẹrẹ :
Ọmọ méjì ni a ń pè ní Ibeji Taiwo, àti Kehinde
Taiye lọ wò bí ilé ayé ṣe rí wa. Leyin na ni Ké hìn de.
Àwọn orúkọ amutorunwa ni yìí :
Ajayi Aina Igẹ Dada
Kehinde Taiwo Idowu Alaba
Orúkọ Abiso:
Ayanbunmi Bolajoko Temilade
Khalid Arinola Kareemot
Orúkọ Oriki:
Akanbi Ishola Abebi Ayinke
Ayinde Ashabi
Presentation Step:
Step 1: Teacher revises the pervious lesson with the learners
Step 2: Introduces the new topic to the learners by explaining the ways of giving name to a child in Yoruba land.
Step 3 : List the different forms of Naming a child with several examples
Evaluation:
1. Dá Orúkọ amutorunwa meji
i. ____________________________________
ii. ____________________________________
2. Kini Orúkọ tí rẹ? ____________________________
3. Dárúkọ Orúkọ Oríkì méjì tí ó mọ :
i. _______________________________
ii. _______________________________
4. _____________________ ni orúkọ amutorunwa. (a) Bolatife (b) Ayinke (d) Aina
5. Orúkọ oríkì ni _________________. (a) Ige (b) Kareemot (d) Abebi
6. _________________ ni àpẹẹrẹ Orúkọ Abiso. (a) Khalid. (b) Akanbi (d) Dada
Conclusion: Ní parí, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ dá orúkọ tí àwọn ènìyàn jẹ lorisirisi gẹ́gẹ́ bí ẹ kò ti wọn ko.