First Term Lesson Note for Week Two
Class: Primary One
Subject : Yoruba
Topic: Alifabeeti Ede Yoruba
Alifabeeti èdè Yorùbá je Meedogbon (25).
Alifabeeti èdè Yorùbá ni ipile kiko àti sísọ èdè Yorùbá bí ó ṣe yẹ.
Àwọn akeeko gbodo ni imọ leta alifabeeti èdè Yorùbá kí ó lè rọrùn fún wọn láti kó àti láti sọ ọrọ Yoruba geerege.
Àwọn leta náà ni wonyii:
LETA ŃLÁ (Big Letters)
A B D E É F
G GB H I J K
L M Ń Ó Ó P
R S S T U W Y
Alifabeeti èdè Yorùbá pín sí ona méjì tíì ṣe Faweli àti Konsonanti
Faweli ede Yoruba je méje ni: A, E, Ẹ , I, O, Ọ, U
Konsonanti èdè Yorùbá je meejidinlogun:
B D F G GB H J K L M Ń P R
S Ṣ T W Y