Third Term Lesson Note for Week Two
Class : Primary One
Subject : Yoruba Studies
Akole : Ásà Imototo Ara
Duration : 40 Minutes (Ogójì iseju)
Period : Single Period
Reference Book :
Alawiiye, Ìwé Kini Láti Owó J. F Odunjo, by Learn Africa.
Lagos State Unified schemes of work for lower Primary Schools, Primary 1 – 3.
Learning Objectives : By the end of the lesson learners will be able to
i. Se alaye ìtumò Imototo Ara.
ii. Dárúkọ ona ti a maa n gba ṣe imototo
Content :
Imototo ni orisirisi ona ti a n gba ṣe itoju ara, àyíká wá àti gbogbo nkan ti o wa ni ile wa.
Imototo dára púpò nítorí ò wún-un ni ó lè bawa Segun àrùn gbogbo.
Àwọn ọ̀nà tí a ń ma gba ṣe imototo.
1. Fò ẹyin rẹ tí ó bá ji
2. Wé gbogbo ara rẹ kí ó mọ saka
3. Ya irun orí rẹ.
4. Gé èékánná owó rẹ tí ó gùn sọbọlọ
5. Gba àyíká ilé re
6. Fò aṣọ rẹ kì ó mọ tonitoni
7. Fò gbogbo àwo tí ó wà ní ìyára ìdáná.
Evaluation :
Dáhùn àwọn ibere wọn yìí :
1. _________________ ni itoju ara, ilé ati àyíká wá. (a) Obun (b) Imototo
2. Imototo le ba wa Segun __________ gbogbo. (a) àrùn (b) ìlera
3. Fò __________ re tí ó bá ji. (a) eekanna (b) eyin
4. Fò ___________ rẹ kì ó mọ tonitoni. (a) aṣọ (b) ẹsẹ
5. _________ eekanna owó rẹ tí ó bá gùn sọbọlọ. (a) Le (b) Ge