First Term Examination
Subject : Èdè Yorùbá
Class: Grade One / Basic One / Primary One
Dáhùn àwọn ìbéèrè wọn yìí lè kún rẹrẹ
1. Di àwọn alifabeeti èdè Yorùbá wọn yìí
A ______ D _______ Ẹ _______ _______
GB H I _______ _______ L _______
O _______ P _______ S S _______ U
W Y
2. Kọ àwọn faweeli èdè Yorùbá
________ _________ _________ _________
________ _________ _________
3. Fala sì di àwọn ónka tí ó yẹ.
i. 10 – ( Èéwa, Éérìn, Eeta)
ìí. 3 – ( Eeta, Eeji, Eesan)
iii. 6 – ( Eejo Eéfà, Eeje)
iv. 4 – ( Eeji, Éérìn, Ookan)
v. 7 – (Eéfà, Èéwa, Eeje)
4. Kọ ọ̀rọ̀ oni lẹ́tà méjì ni óna márùn-ún.
i. ________________. ii. ________________
iii. _______________ iv. _______________
v. _______________
5. Fala sidi orúkọ àwọn nkan ti o wa ninu ọgbà ilé ìwé wá ní èdè Yorùbá.
i. Classroom – ( Yara ikawe, Yàrá íbusun )
ii. Drum – ( Aṣọ, ìlú )
iii. Flower – (Òdòdó, Odada )
iv. Gate – ( Geeti, Gaati )
v. Chair – ( Aga, Ajá )
6. Di àwọn àlàfo orín yìí :
Ojo ń _______. Ṣere _______ ile
Má _______ nù ________. Kí aṣọ ________
Ma _______ tútù. Kí ________ ma bá _______ ó.