First Term Lesson Note
Class : Primary
Subject : Yoruba
Topic : Ikini Laarin Odun.
Duration : 80 Minutes
Period : Double periods
Reference Book :
Eko ede Yoruba fun Primary.
Instructional materials :
Learning Objectives : By the end of the lesson, learners will be able to :
i. Se alaye itumo ikini Laarin odun
ii. Daruko igba ikini ati idahun.
Content :
Ikini tumo si Greetings lede Geesi.
Igba tumo si Season/ period lede Geesi.
Igba meta lo WA ninu odun Kan.
Awon Igba naa niyi :
a.) Igba Ojo – ( Rainy Season)
b.) Igba Eerun – (Dry Season)
d.) Igba Oye – ( Harmattan Season)
Orisirisi Ikini lo WA fun Igba kookan.
Awon Ikini naa lo bayii :
a.) Igba Ojo – E ku Ojo yi o! / Ojo itura ni yoo Je o!
Idahun – Amin ooo!
b.) Igba Eerun – E ku Eerun yi o! / E ku ogbele yi o!
Idahun. – Ooo!!!
d.) Igba Oye – E ku Oye yi o! / E ku otutu yi o!
Idahun – Ooo!!!
e.) Igba Odun – E ku odun o! Emi wa yoo se pupo odun laye o!
Idahun – Amin ooo!
I love this
Cuz it’s more explanative