Class : Nursery One
Age : 4 years
Subject : Yoruba Language
Topic : Ìwúlò omi
Duration : 80 minutes
Period : Double Periods
Reference Book :
Eko èdè Yorùbá fún Ilé ìwé alakobere, Ìwé ikinni
Lagos State Unified Schemes of Work for Early childhood .
Online Resources
Instructional Material : Ìwé èdè Yorùbá, àwòrán omi
Behavioural Objectives : By the end of the lesson learners will be able to : Nipari ẹ̀kọ́ , àwọn akeeko gbodo mo
i. So ìtumò omi
ii. Dárúkọ àwọn ìwúlò omi
Content :
Omi je ohun ti o funfun tí kò sì mi abawon tàbí idoti nínú.
Ìwúlò Omi
1. Omi dá lára fún mímú.
2. A máa ń fi omi fi aṣọ wa
3. Omi dára fún oúnjẹ sise
4. A máa ń fi omi wé .
5. Omi má je ki awon nko tí a gbìn kò hu dada.
Presentation Steps :
Step 1 : Atunyewo eko ṣáá tó kọjá pelu àwọn akeeko.
Step 2 : Oluko ṣe àfihàn àkòrí tuntun , òsì ṣe àpèjúwe Omi.
Step 3 : Oluko ṣe àlàyé fún àwọn akeeko bí wọn ṣe ń lo omi àti ìwúlò rẹ.
Evaluation :
1. Kí ni Omi je?
2. Dárúkọ ohun merin tí a lè fi omi ṣe.
Conclusion : Oluko ṣe Atunyewo eko na pelu awon akeeko.
Assignment :
Dárúkọ ìwúlò omi mẹta tí ó mọ .