First Term Lesson Note for Week
Class : Nursery Two
Subject : Yoruba Studies
Topic : Orin nipa Iya. (Iya ni wura iyebiye)
Duration :
Period :
Reference Book :
Learning Objectives : By the end of the lesson, learners will be able to :
i. Sing the song (ko Orin akomo ni wa ni Pa Iya.
ii. Won a si so itumo awon oro ti o wa ninu Orin naa.
Content :
IYA NI WURA IYEBIYE
Iya ni wura iyebiye,
Ti a ko Le fowo ra. [ twice 2x]
Oloyun MI fosu mesan-an.
O pon MI fodun meta.
Kin ni n ba fowo ra,
To Le leke?
Iya to bi mi lomo o!
IGBELEWON :
Ko oro wonyi lede Geesi :
1.) Wura – ____________________
2.) Bowo – _____________________
3.) Igboran – ____________________
4.) Ta a ni a ko Le fowo ra? ______________
5.) Odun meloo ni Iya fi pon omo seyin?
_____________________________