FIRST TERM LESSON NOTE FOR NURSERY
ṢÁÁ IKINNI NÍNÚ ỌDÚN FÚN ÀWỌN ỌMỌ ỌDÚN MẸ́RIN
AGE: 4 YEARS
SUBJECT: YORÙBÁ
TOPIC: KIKO ÀTI KIKA ALIFABEETI NÍ ÈDÈ YORÙBÁ LÁTI A – Ẹ. (Reading and writing of alphabet A – Ẹ in Yoruba)
DURATION : 80 MINUTES
PERIOD : Double Periods
REFERENCE BOOK :Online Resources
Lagos State scheme of work for early childhood.
Instructional Material : Chart on the alphabets in Yoruba.
Behavioural Objectives: By the end of the lesson, learners will be able to:
i. Kò àti ká alifabeeti Yoruba daradara (read and write the alphabet a – ẹ in Yoruba)
ii. Ṣe adamọ àwọn lẹ́tà pelu àwòrán. (Identify the alphabet a – ẹ with objects)
Content:
A B D E Ẹ
A – Ajá
B – Bàtà
D – Dòdo
E – Ewe
Ẹ – Ẹye
Presentation Step:
Step 1: Review of the previous knowledge
Step 2: Introduction of the new topic
Step 3: Explanation of the topic ( Aláyè lórí kika alifeebeti a – ẹ)
Evaluation:
1. Kí akeeko jáde láti ṣe àfihàn lẹ́tà sì ojú pátákò ìkọ̀wé
a b d e ẹ
2. Kí akeeko dárúkọ àwọn àwòrán tí ó romo àwọn lẹ́tà a – ẹ
Conclusion: Nipari Oluko ṣàlàyé ẹ̀kọ́ na láti ìbéèrè titi de òpin.