First Term Lesson Note for Week Six
Class: Nursery One
Age: 4 years
Subject : Yoruba Language
Topic: Kíkún Àwòrán ni kolo
Duration : 80 minutes
Period : Double Periods
Reference Book :
- Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá for Nursery Book 1
- Lagos State Unified Schemes of Work for Early childhood
- Online Resources
Instructional Material : Charts on images of different things.
Behavioural Objectives : By the end of the lesson, learners will be able to :
i. Àwọn akeeko gbodo dá kolo mo
ii. Kún àwòrán pelu orisirisi kolo
Previous Knowledge: Àwọn akeeko tí kò ní pá onka èdè Yorùbá.
Content:
Orisirisi àwọn kolo ni ó wà. Kolo ni a máa lo láti fi jẹ ki àwòrán tí a bá yá dára púpò.
Fún àpẹẹrẹ :
1. Àwo dúdú – Black colour 🖤
2. Àwo funfun – White colour. ☕
3. Àwo Pupa – Red colour. 🌹
4. Àwo èwe – Green colour. 🍏
Dárúkọ kolo awon Àwòrán wonyii kí ó sì fà ìlà sidi eleyi ti o dahun ìbéèrè náà.
1. 🍓🍒🍅 _________ ( àwo dúdú, àwo Pupa)
2.🫑🥦🥬 ___________ (awo funfun, àwo ewe)
3. 🏐☕ _____________ (àwo dúdú, àwo funfun)
4. 🖤🕶️🏴 ___________ ( àwo dúdú, àwo èwe)
Presentation Step:
Step 1: Revision of the previous week Lesson with the learners by asking questions orally.
Step 2: The teacher introduces the new topic by defining colours
Step 3: The teacher list the types of colour and asks the learners to colour some objects.
Evaluation: The teacher reviews the lesson by asking questions as follows:
Kún àwọn aworan yìí pelu kolo
i. Dúdú 🏐
ii. Èwe. 🍀
iii. Pupa. 📖
iv. Funfun ☕
Conclusion: The teacher explains the topic all over again to the learners.
Nípari, akeeko àti oluko dá orúkọ àwọn kolo tí wọn mo.