Third Term Lesson Note for Week Two
Ise Ṣáá Keta fún ose kejì.
Class : Primary Three
Subject : Yoruba Studies
Topic : Litireso Alo Apamo
Duration : 40 Minutes
Period : Single Period
Reference Book :
Ìwé Alawiye fún Ede Yoruba, Ìwé Keta
Lagos State Unified schemes of work for lower Primary Schools, Primary 1 – 3.
Instructional Material : Àwòrán tí ó ṣe àlàyé Alo apamo àti ìtumò pelu apeere
Learning Objectives : By the end of the lesson learners will be able to
i. So ìtumò Alo Apamo
ii. Se alaye Alo Apamo orisirisi
Content :
Kini a npe Alo Apamo?
Alo Apamo ni alo tí a pa, tí a sọ ìtumò rẹ lesekese, a fi ńṣe àkàwé oro ni.
Orisirisi Alo Apamo ati ìtumò wọn :
1. Alo ó, aalo, kílo ba ọba jẹun tí kò ipalemo? Kii ni ó? itumo: Esinsin
2. Alo o, Aalo o, kílo kọjá ní iwájú ọba tí kò ki ọba? Kínní ó! : Agbára ojo
3. Alo ó, Aalo ó, oruku tíndín tíndín, oruku tindin tindin oruku bí ìgbà ọmọ, gbogbo wọn lọ lè tiro, kii ni? Ìtumò : Eree / Ewa
4. Alo o, Aalo, kílo kan ọba ní kó, kii ni ó? Ìtumò : Abé ifari
5. Alo o, Aalo, opo bàbà Alo kan láéláé, opo baba Alo kan láéláé, ọjọ́ tó bá de fìlà Pupa ni, ikúde ba, kii ni ìtumò : Abela / Siga
6. Alo ó, aalo, ilé gbajumo, kìkì ìmí ẹran, kii ni ó? Ìtumò : Ibepe.
Evaluation :
1. _________________ ni alo tí a pa, tí a sọ ìtumò rẹ lesekese, a fi ńṣe àkàwé oro ni. (a) Alo Apamo (b) Alo Apagbe
2. Alo ó, aalo, ilé gbajumo, kìkì ìmí ẹran, kii ni ó? Ìtumò ni ____________. (a) abela (b) ibepe (d) Abe ifari.
3. Alo ó, Aalo ó, oruku tíndín tíndín, oruku tindin tindin oruku bí ìgbà ọmọ, gbogbo wọn lọ lè tiro, kii ni? Ìtumò : _________________. (a) Eree / Ẹwà (b) Abela (d) Abe ifari
4. Kílo kọjá ní iwájú ọba tí kò ki ọba? Kínní ó! __________________. (a) Eṣinṣin (b) Agbára ojo (d) Ewa