Second Term Lesson Note for Week Three
Class : Nursery One
Age : 4 years
Subject : Yoruba Language
Topic : Onka èdè Yorùbá láti 6 – 10 .
Duration : 80 minutes
Period : Double Periods
Reference Book :
- Eko Ede Yoruba fún Alakobere
- Lagos State Unified Schemes of Work for Early childhood .
- Online Resources
Instructional Material : Ìwé èdè Yorùbá , Onka láti eéfà titi de eewa.
Behavioural Objectives : Ní ìparí ẹ̀kọ́ , àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gbodo mo:
i. Kika onka èdè Yorùbá láti eéfà titi de eewa.
ii. Bí wọn ṣe kó onka èdè Yorùbá
Previous Knowledge : Àwọn akeeko le ka onka èdè Yorùbá láti oókan títí dé aarun
Content :
Ká onka èdè Yorùbá láti 6 titi de 10.
Eéfà – 6
Eeje – 7
Eejo – 8
Eesan – 9
Eewa – 10
Oluko kò orin onka èdè Yorùbá sì etí igbó àwọn akeeko.
Presentation Steps :
Step 1 : Oluko se atunyewo eko ṣáá tó kọjá pelu awon akeeko.
Step 2 : Oluko ṣe àfihàn àkòrí tuntun, òsì ṣe àlàyé fún àwọn akeeko.
Step 3 : Oluko sì kó àwọn akeeko bí wọn ṣe lè ka onka èdè Yorùbá. Ó sì kó wọn ní orin ni pá onka èdè Yorùbá .
Evaluation :
Dáhùn àwọn ìbéèrè wonyii:
Ká àwọn àwòrán wọn yìí, kí ó sì fala sidi onka tó jẹ́ mo wọn.
1. 🍎🍎 (a) Oókan (b) Eeta (d) Eeji
2. 🍉🍉🍉🍉 (a) Eerin (b) Eeta (d) Ookan
3. 🏀 (a) Eeji (b) Oókan (d) Eeta
4. 🚪🚪🚪🚪🚪🚪 (a) Eéfà (b) Eewa (d) Eeta
5. 🥚🥚🥚🥚🥚🥚🥚🥚🥚 = ________________
(a) Eeje (b) Eewa (d) Eesan
Conclusion : Oluko ṣe atunyewo eko na pelu awon akeeko kí ó lè rí dájú wí pé eko náà yẹ wọn daradara.
Assignment :
Ká àwọn àwòrán yìí, kí ó sì fà ìlà sì abé ẹṣin tó yẹ.
1. 🍿🍿🍿🍿🍿🍿🍿 = _______________
(a) Eeje (b) Eéfà (d) Eeta
2. 🚑🚑🚑🚑🚑🚑🚑🚑🚑🚑 = _____________
(a) Eeji (b) Eewa (d) Eesan
3. 🌹🌹🌹🌹🌹🌹🌹🌹 = ______________
(a) Eéfà (b) Eerin (d) Eejo