Third Term Lesson Note for Week Four
Class : Primary Two
Subject : Yoruba Studies
Topic : Òwe ni ile Yoruba
Duration : 40 Minutes
Period : Single Period
Reference Book :
- Alawuiye Ìwé Kejì By J. F. Odunjo
- Lagos State Unified schemes of work for lower Primary Schools, Primary 1 – 3.
- Online Resources
Instructional Material : Fiditi ó fi àwòrán eko hàn lórí òwe.
Learning Objectives : Ní Ìparí eko yìí, akeeko gbodo mo :
i. Ìtumò òwe ni ile Yoruba
ii. Se àpẹẹrẹ owe tí wọn ba mọ
Content :
Lawujo Yoruba a máa ń gbó gbólóhùn ba yii: Owe lè sìn oro, oro lè sìn òwe, bí oro bá sọnù, òwe là fín wá.
Òwe ṣe pàtàkì púpò lawujo Yoruba. Bí ọmọdé bá pá òwe ni iwájú àgbàlagbà, a sọ pé tótó ó ṣe bí òwe, àgbàlagbà tó bá wá nibe náà a sọ pé wàá pá òmíràn tàbí òwe ni wàá pá ó lọ míì pá ènìyàn.
Àpẹẹrẹ àwọn òwe ni ile Yoruba ni wọn yii :
1. Ona òfun lo ona ọrùn
Ìtùmò : Kò sí ohun tí eda ko le se lati wa oúnjẹ oojo.
2. Ọgbọ́n ologbon kii je ki a pé àgbà ní were
Ìtùmò : Kò wúlò rarki a gbon tán kí a kò láti máa mú ọgbọ́n ẹlòmíràn lo
3. Ìgbà kii tó lọ bí ó rere, ayé ki tó lọ bí ọ̀pá ìbon.
4. Ojú ẹni maa là á rí ìyọnu,
Ìtùmò : Wàhálà lọ koko máa ń síwájú kí ènìyàn Tóò di oloro
5. Ìkòkò tí yóò jata, ìdí rẹ a gbona
Itumo : Ènìyàn gbodo ṣe wàhálà lọpọlọpọ tí o bá fẹ́ joró lọ́jọ́ iwájú.
6. Màlúù tí kò ní ru Olúwa lọń m bàa le eṣinṣin.
Ìtùmò : Òwe yìí ń fi yẹ wá Olúwa lọ máa ń rán eniyan ti ko ba ni oluranlowo lowo.
Presentation Steps :
Step 1 : Se alaye ranpe lọ rí eko tí ó koja seyin pelu ìbéèrè
Step 2 : Oluko ṣe àlàyé òun ti a npe í òwe ni ile Yoruba.
Step 3 : Àwọn akeeko sì dárúkọ àpẹẹrẹ òwe ni orisirisi.
Step 4 : Oluko sì ṣe alaye ìtumò owe fún àwọn akeeko
Evaluation :
1. _____________ le shin oro, oro lè sìn òwe.
2. Bí oro bá sọnù kí ni a fi ń wá? ______________
3. Malu tí ó ní irú, ____________ ni ó nba lè eṣinṣin. (a) ènìyàn (b) Olúwa (d) Ọmọ
4. Ojú ẹni má là á rí ______________. (a) Itoju (b) Ìyọnu (d) Isonu.
Conclusion : Oluko tún ṣe àlàyé lekun rere fún àwọn akeeko.