First Term Examination
Class : JSS 2
Subject : Yoruba
Topic : Examination
Duration : 2 Hours
ÌPÍN KINNI (Part One)
Ilana: Dáhùn gbogbo ìbéèrè kí ìpín yìí. Ká àyọkà isale yìí, kí ó sì dáhùn ìbéèrè tí ó tẹ́lẹ̀ ẹ.
Orúkọ tí a sọ ọmọ ṣe pàtàkì púpò nínú àsa Yoruba. Ìdí niyi ti Yoruba fi ní àwọn orúkọ tí wọn ń pè ní orúkọ amutorunwa. Yorùbá a máa wò ipò àti ona ti ọmọ gba wáyé láti fún ọmọ bẹẹ ni orúkọ amotorunwa.
Ọmọ méjì tí wọn wáyé láti inú ìyá kan, èyí tí wọn koko bí ní Taiwo, èkejì ni Kehinde. Èyí tí a bí tẹ́lẹ̀ àwọn ìbejì ni Idowu, òun sì ni Yoruba tún máa ń pe ni Èṣù leyin ìbejì. Àbúrò Idowu ni Alagba. Àbúrò Alaba ni Idogbe.
Yoruba à tún máa wò ipò tí ọmọ bá wáyé láti fún wọn lórúko. Omo tí ó wà nínú àpò ni Òkè. Ajayi ni ọmọ tí ó dojú olè nígbà tí wón bíi. Omo tí ó ní ìlà ese mefa ni Olugnobi. Ojo ni ọmọ tí ó gbé ibi kọrin wáyé, tí ó bá jẹ obìnrin wọn a sọ ó ní Aina.
Ibeere
1. Kínní Yoruba ń pè ọmọ tí a bí tẹ́lẹ̀ ìbejì? (a) Alaba (b) Idogbe (d) Idowu (ẹ) Kehinde
2. Ẹni tí a ń pè ní èṣù leyin ìbejì ni _____________. (a) Taye (b) Òkè (d) Idowu (ẹ) Idoha
3. Àkíyèsí wo ni Yoruba máa ń rí lára ọmọ kí wọn tó sọ ó ní òkè? (a) Òun ni àbí tẹ́lẹ̀ ìbejì (b) Ọmọ tí ó wà nínú àpò (d) Ọmọ tí ó dojú bolè (ẹ) Ọmọ tí kò waye
4. Omo tí ó ní ìkà ese ________ ni Yoruba ń pè ní Olugbodi. (a) Merin (b) Mefa (d) Méje (ẹ) Mesan-an
5. Akole tí ó bá àyọkà yìí mú ju ni ___________. (a) Orúko amutorunwa (b) Orúkọ isedale (d) Ásà Yoruba (ẹ) Ásà Ọmọ Idile
6. “Dide” je àpẹẹrẹ gbólóhùn. (a) Àṣẹ (b) Oniroyin (d) Ìbéèrè (ẹ) Asinpo
7. Gbólóhùn _________ ni a fi ń béèrè ohun kan tàbí òmíràn. (a) ìròyìn (b) Kani (d) ìbéèrè (ẹ) Ase
8. Igbese àkókò nínú àṣà ìgbéyàwó abinibi ni _________. (a) Ìwádìí (b) Ipalemo (d) Ifojusode (ẹ) Ilana
9. _________ ni ẹni tí ó máa ń ṣe agbenuso laarin ọkọ àti ìyàwó afesona. (a) Abenugan (b) Alárinà (d) Alamojuto (ẹ) Ikini
10. Ìgbéyàwó ________ fi àyè gba kí ọkọ fe ìyàwó méjì tàbí ju bee lọ. (a) Soosi (b) Musulumi (d) Kóòtù (ẹ) Ilé Naijiria
11. Ìgbéyàwó òde-òní wáyé nípasẹ̀ ________ àti _________. (a) Olaju àti Ẹṣin àjòjì (b) Olaju àti ìfẹ́ inú (d) Owó àti ipò (ẹ) Ipò àti egbe
12. Àpẹẹrẹ gbólóhùn wo ni a fala sì yìí? Aṣọ tí oloko ibi wo dára. (a) Gbólóhùn ó ibo asepejuwa (b) Gbólóhùn ọmọ ó àṣàponle (c) Gbólóhùn alakanpo (d) Gbólóhùn ó ibo kani
13. Ise gbólóhùn ________ ni lati se àfikún alaye lori oro – ise. (a) Gbólóhùn ónibo aṣàpèjúwe (b) Gbólóhùn alakanpo (d) Gbólóhùn ónibo asaponle (ẹ)
14. “Laide du ata lo ta ni oja” je apeere gbólóhùn __________. (a) Alakanpo (b) Àṣẹ (d) Gbólóhùn kani (ẹ) Olopo oro-ise
15. Àpẹẹrẹ gbólóhùn wo ni èyí? “Ó lọ sugbon ko jẹun.” (a) Gbólóhùn alakanpo (b) Gbólóhùn olopo ìṣe (d) Gbólóhùn abode (ẹ) Gbólóhùn alaye
16. Èwo ni kii se ise àkànṣe Yoruba nínú àwọn wonyii? (a) ìṣe darandaran (b) Ìṣe ẹni híhun (d) ìṣe ìkòkò mimo (ẹ) ìṣe alaro
17. Ise ìkòkò mimo sáábà máa ń jẹ ìṣe àwọn ___________. (a) odobinrin (b) ọkùnrin àgbàlagbà (d) obìnrin àgbàlagbà (ẹ) omode
18. Orúkọ mìíràn tí a tún máa ń pe litireso a lóhùn _____________. (a) Litireso Ìkíni (b) Litireso apileko (d) Litireso ọmọdé (ẹ) Litireso atenudenu
19. Èwo ni litireso a lóhùn tó jemo ayẹyẹ nínú àwọn èyí? (a) Sango pipe (b) Bolojo (d) Alo (ẹ) Obatala
20. Ogun mélòó ni ó wà nínú Ogojo? (a) Ogun mefa (b) Ogun mejo (d) Ogun kẹsàn-án (ẹ) Ogun meji
21. Ìgbà mélòó ni ó wà nínú irínwó? (a) Méjì (b) Mẹta (d) Merin (ẹ) Mefa
22. A je agbado: A jẹ oro-aropo orúkọ ni ipo _______ (a) Olúwa (b) Abo (d) Enikeji (ẹ) Eyan
23. Kínní Yoruba ń pè ní irínwó? (a) 400 (b) 500 (d) 600 (ẹ) 800
24. “Oodun-run” ni Yoruba ń pè ____________. (a) 200 (b) 250 (d) 300 (ẹ) 700
25. Yorùbá gbàgbó pé ________ ní èrè igbeyawo. (a) Owó (b) Ọmọ (d) Aṣọ (d) Eekanna
26. Ọkàn lára itoju oyún ni ona abinibi ni èyí (a) Gbigba abere (b) Lílọ èwe àti egbò igi (d) Lilo soosi (ẹ) Lílọ ìdí sango
27. Dìde oyún je àṣà itoju oyún àti dènà ________. (a) Wíwà sílè laito ojo (b) Kí inú máa rò alaboyun (d) Kí alaboyun má fi ikùn gbale (ẹ) Lílọ sì ilé iwosan
28. Eewọ tí ìyà ọmọ tuntun kò gbogbo ja máa ń jẹ _________. (a) eewọ oro ìdílé bàbà ómo (b) eewọ oro ìlú (d) eewọ alabagbele (ẹ) Ọmọ náà yóò jo
29. Lára ohun tí ó fà eewọ ìdílé fún ìyá ọmọ tuntun láyé àtijó ni _________. (a) Gbajumo sise (b) ibagbepo ebi (d) òwú jíjẹ (ẹ) Ẹni kinni
30. Lára ohun – èlò isomoloruko ni èyí (a) ata (b) aṣọ (d) oyin (ẹ) igun
31. Fífi “ẹja-aro” ṣe àdúrà fún ọmọ tuntun túmọ̀ sí pé (a) Ọmọ náà yóò darúgbó (b) Ọmọ náà yóò fi ori là gbogbo ìṣòro ayé rẹ ja (d) Ọmọ náà yóò feran ẹja-aro púpò (ẹ) Ọmọ náà yóò máa jẹ eja
32.Odun wo ni ifohunsokan wáyé lórí akòtò èdè Yorùbá? (a) 1974 (b) 1966 (d) 1984 (ẹ) 1999
33. Fífi “orogbo” ṣe àdúrà fún ọmọ tuntun túmọ̀ sí ________. (a) pé ọmọ náà yóò feran jíjẹ orogbo (b) pé ọmọ náà yóò dàgbà (d) pé ọmọ náà kò ní feran orogbo rárá (ẹ) Lílọ ìdí sango
34. Ọkàn lára ifohunsokan lórí akoto èdè Yorùbá ni pé (a) konsonanti méjì kó gbodo tẹ́lẹ̀ ara wọn nínú ọ̀rọ̀ kan (b) faweli méjì kó gbodo jókòó papọ nínú ọ̀rọ̀ kan (d) faweli nìkan ni Yoruba (ẹ) Faweli àti konsonanti
35. Yorùbá gbàgbó pé ________ máa ń rò ọmọ. (a) owó (b) ipò (d) orúkọ (ẹ) Ẹni kan soso
36. Orúkọ abiso ni ________ je. (a) Taiwo (b) Ajayi (d) Adeyemi (ẹ) Ajayi Olu
37. Irúfé Orúkọ wo ni èyí ” Durojaye”? (a) Orúkọ abiso (b) Orúkọ Ìdílé (d) Orúkọ amutorunwa. (ẹ) Orúkọ abiku
38. Ọkàn nínú àwọn ọ̀rọ̀ wọnyi kò bá ìlànà akoto mú. (a) Oúnjẹ (b) Aiye (d) Obìnrin (ẹ) Okunrin
39. Èwo ni ó bá òfin akoto èdè Yorùbá mú nínú àwọn wonyii? (a) oshogbo (b) Osogbo (d) Osogbbo (ẹ) Ohsogbo
40.
ÌPÍN KEJI (Part Two)
ILANA: Dáhùn ìbéèrè Merin ni Ìpín yìí. Ìbéèrè àkókò je dandan
1a. Kini Gbólóhùn?
1b. Dárúkọ eya gbólóhùn tí ọ̀kọ̀ọ̀kan gbólóhùn isale yìí je:
i. Adé je eba. ________________________________
ii. Adé je eba yọ. ______________________________
iii. Ó lowo àmọ́ ko kólé. _______________________
iv. Òde paberan sún je lóko. __________________
v. Ó kàwe sugbon ko ri ìṣe. ____________________
vi. Olè gbé ade ọba. __________________________
vii. Kani mo lowo, maá ti kólé. _________________
viii. Olú kò jẹun sún lànà. _____________________
ix. Fake ariwo. _______________________________
x. Ǹjẹ́ o ti jẹun? _______________________________
2. Kò àwọn igbese àsa ìgbéyàwó abinibi ni sise-n-tele
3a. Dárúkọ ohun – èlò isomoloruko márùn-ún.
3b. Ṣàlàyé bí a ṣe ń lọ mẹta nínú re:
4a. Kò orúkọ abiso márùn-ún tí ó mo:
4b. Kò márùn-ún nínú orúkọ amutorunwa.
5. Tún àwọn ọ̀rọ̀ wọnyi kò ní ilana akoto èdè Yorùbá.
i. Onje – ____________________
ii. Enia – ____________________
iii. Oshun – __________________
iv. Nigbati – _________________
v. Lailai – ____________________
vi. Olopa – ___________________
vii. Aiye – ___________________
viii. Offa – ___________________
ix. Nitoripe – ________________
x. Osogbo – _________________